Àti pé nínú òru, fi kíké al-Ƙur’ān (lórí ìrun) ṣàì sùn. (Èyí jẹ́) iṣẹ́ àṣegbọrẹ fún ọ. Láìpẹ́, Olúwa rẹ yóò gbé ọ sí àyè ọpẹ́.
____________________
Àyè ọpẹ́ yìí dúró fún àyè ìṣìpẹ̀ fún gbogbo ẹ̀dá tí ó máa jẹ́ ti Ànábì wa Muhammad (sollalāhu 'alayhi wa sallam) nìkan ṣoṣo ní Ọjọ́ Àjíǹde.


الصفحة التالية
Icon