Wọn kò sì lè ṣe àrànṣe fún wọn; ṣebí àwọn òrìṣà ni ọmọ ogun tí A máa kó wọ inú Iná fún àwọn abọ̀rìṣà (láti fi jẹ wọ́n níyà).
____________________
Ẹ wo sūrah Mọryam; 19:82 àti sūrah al-’Anbiyā’; 21:98.


الصفحة التالية
Icon