A máa ṣẹ́gun ọmọ ogun t’ó wà níbẹ̀ yẹn nínú ọmọ ogun oníjọ.
____________________
Èyí ni àdéhùn ìṣẹ́gun fún Ànábì (sollalāhu 'alayhi wa sallam) àti àwọn mùsùlùmí lórí àwọn ọ̀tá ’Islām. Irú àdéhùn yìí tún wà nínú sūrah al-Ƙọmọr; 54:45.


الصفحة التالية
Icon