Àwọn ni àwọn t’ó ń wí pé: “Ẹ̀yin kò gbọ́dọ̀ ná owó fún àwọn t’ó wà lọ́dọ̀ Ójíṣẹ́ Allāhu títí wọn yóò fi fọ́nká. Ti Allāhu sì ni àwọn àpótí-ọrọ̀ sánmọ̀ àti ilẹ̀, ṣùgbọ́n àwọn ṣọ̀bẹ-ṣèlu mùsùlùmí kò níí gbọ́ àgbọ́yé.


الصفحة التالية
Icon