ﰚ
                    surah.translation
            .
            
    
                                    من تأليف: 
                                            أبو رحيمة ميكائيل أيكوييني
                                                            .
                                                
            ﰡ
Sọ pé: "Ẹ̀yin aláìgbàgbọ́,
                                                                        Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ̀ ń jọ́sìn fún.
                                                                        Ẹ̀yin náà kò jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún.
                                                                        Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ jọ́sìn fún sẹ́.
                                                                        Ẹ̀yin náà kò kú jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún.
                                                                        Tiyín ni ẹ̀sìn yín, tèmi sì ni ẹ̀sìn mi."