وَمَآ أَصَٰبَكُم مِّن مُّصِيبَةࣲ فَبِمَا كَسَبَتۡ أَيۡدِيكُمۡ وَيَعۡفُواْ عَن كَثِيرࣲ ٣٠
Ash-Shura 42:30
سورة الشورى
Meccan
Verse: 30/53
Page 486
-
Yorùbá translation
الترجمة اليورباوية
Ohunkóhun tí ó bá kàn yín nínú àdánwò, ohun tí ẹ fi ọwọ́ ara yín fà ni. Ó sì ń ṣàmójúkúrò níbi ọ̀pọ̀lọ́pọ̀.
Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ fún sūrah an-Nisā’; 4O:79.
Ash-Shura 42:30
Loading the recitation…
0:00