ترجمة سورة العصر

الترجمة اليورباوية
ترجمة معاني سورة العصر باللغة اليورباوية من كتاب الترجمة اليورباوية .
من تأليف: أبو رحيمة ميكائيل أيكوييني .

Allāhu búra pẹ̀lú àkókò ìrọ̀lẹ́ ayé.
Dájúdájú ènìyàn wà nínú òfò.
Àyàfi àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n ṣe àwọn iṣẹ́ rere, tí wọ́n sọ àsọtẹ́lẹ̀ òdodo láààrin ara wọn, tí wọ́n sì tún sọ àsọtẹ́lẹ̀ sùúrù láààrin ara wọn.
Icon