سورة الكوثر

الترجمة اليورباوية

Ìtumọ̀ Sura الكوثر ní اليورباوية láti الترجمة اليورباوية

الترجمة اليورباوية

Verse 1
Dájúdájú Àwa fún ọ ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ oore.
Verse 2
Nítorí náà, kírun fún Olúwa rẹ, kí o sì gúnran (fún Un).
Verse 3
Dájúdájú, ẹni t’ó ń bínú rẹ, òun ni kò níí lẹ́yìn.
تقدم القراءة