Ìtumọ̀ Sura الفلق ní اليورباوية láti الترجمة اليورباوية
Verse 1
ﭤﭥﭦﭧ
ﭨ
Sọ pé: "Mo sá di Olúwa òwúrọ̀ kùtùkùtù
Verse 2
ﭩﭪﭫﭬ
ﭭ
níbi aburú ohun tí Ó dá,
Verse 3
ﭮﭯﭰﭱﭲ
ﭳ
àti níbi aburú òru nígbà tí ó bá ṣóòkùn,
Verse 4
ﭴﭵﭶﭷﭸ
ﭹ
àti níbi aburú àwọn (òpìdán) t’ó ń fẹnu fátẹ́gùn túẹ́túẹ́ sínú àwọn ońdè,
Verse 5
ﭺﭻﭼﭽﭾ
ﭿ
àti níbi aburú onílara nígbà tí ó bá ṣe ìlara."
تقدم القراءة