ع Ìtumọ̀ Sura الكوثر ní اليورباوية láti الترجمة اليورباوية الترجمة اليورباوية الترجمة اليورباوية الذهاب لصفحة الكتاب Verse 1 ﮆﮇﮈ ﮉ Dájúdájú Àwa fún ọ ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ oore. Verse 2 ﮊﮋﮌ ﮍ Nítorí náà, kírun fún Olúwa rẹ, kí o sì gúnran (fún Un). Verse 3 ﮎﮏﮐﮑ ﮒ Dájúdájú, ẹni t’ó ń bínú rẹ, òun ni kò níí lẹ́yìn. تقدم القراءة تحميل المزيد عرض الكل