ترجمة سورة النّاس

الترجمة اليورباوية
ترجمة معاني سورة النّاس باللغة اليورباوية من كتاب الترجمة اليورباوية .
من تأليف: أبو رحيمة ميكائيل أيكوييني .

Sọ pé: "Mo sá di Olúwa àwọn ènìyàn,
Ọba àwọn ènìyàn,
Ọlọ́hun àwọn ènìyàn,
níbi aburú (Èṣù) oníròyíròyí, olùsásẹ́yìn (fún ẹni t’ó bá dárúkọ Allāh).
(Èṣù ni) ẹni tí ó ń kó ròyíròyí sínú àwọn ọkàn ènìyàn.
(Èṣù náà) wà nínú àlùjànnú àti ènìyàn.
Icon